YORUBA CHURCH

ABUNDANT LIFE GOSPEL CHURCH (YORUBA CHURCH)
2017 PLAN (AWON ETO ATI ILEPA WA FUN ODUN 2017)

  1. Atun ma tesi waju ninu awon eto wa larin osese ojo Isegun ati Ojobo, ni dede akoko ti a ma npade (Tuesdays 5:30pm -6:30pm (Eko Bibeli) & Thursdays (8:00am – 10:00am)
  2. Ni Gbogbo Ojo Jimo akoko ninu Osu titun (First Friday of Every Month). Iso oru Yoruba yo ma waye.
  3. Ni Osu meta, meta lamanse isoji. Akori: OLORUN JE KI NJE AJEYO ATI AJESEKU. OLORUN JE KI NI ANITO ATI ANISEKU. 31/1 si 2/2, 2017, 30/5 si 1/6, 2017, 19/12 si 21/12, 2017.
  4. Ninu Odun yi a ma jade fun ihinrere nigba merin ki Odun yi to pari, ki Olorun fun wa se.
  5. Iso oru olojo merinla wa mawaye lo dun yi bakan na, o ma bere ni Ojo Kerinlelogun Osu Kejo si Ojo Kejo Osun Kesan, Odun, odunyi, 17/8 si 1/9, 2017. (Iwe Awon Oba Kini 17:14-16) (1King 17:14-16)
  6. A ma ni akanse eto Ojobo Meje. Akori – Gbigba Ogo Mi Pada. (Orin-Dafidi 126). Special Programme 7 Thursday o ma bere ni Ojo Kesan Osu Kokanla si Ojo Kokanlelogun Osun kejila, 9/11 si 21/12/2017. Eto yi ni a ma fi pari Odun yi 2017.

Adura wa ni ki Emi-Mimo tiwa leyin fun aseyori, ayo lafi bere Odun yi, idunnu ati alaafia lama fi pari e loruko Jesu. Amin

IDUPE – Modupe lowo Olorun, Baba, Olorun Omo ati Olorun Emi Mimo

Rev. Mrs Janet Onaolapo (General Oversea)

Pastor Raphel (Pastor-In-Charge, Yoruba Service)